Adura Ope Si Olorun (Prayers of Thanksgiving)

E-Reporters
0


Prayers of Thanksgiving - Adura Ope Lowo Olorun

Giving thanks to the Lord is our lifestyle as God’s children. The bible says, “In all things give thanks; for this is the will of God in Christ Jesus concerning you all”, (1 Thessalonians 5:18). Psalm 136:1 says, “Give thanks to the LORD, for He is good; For His loving-kindness (graciousness, mercy, compassion) endures forever”.  Right now, let’s thank and praise God. He is worthy to be praised. Halleluiah!

Fifun Oluwa ni iyin je igbe aye awa m lrun. Bíbélì s pé, “Nínú ohun gbogbo, ki a máa dúpẹ́; nítorí èyí ni ìfẹ́ lọ́run nínú Kristi Jésù fun wa” (1 Tsalóníkà 5:18). Psalm 136:1 wipe, “ fi p fun Oluwa, nitoriti o eun; Nítorí tí inú-rere rẹ̀ (oore-ọ̀fẹ́ ati àánú) dúró títí láé.” Ni bayi, j ki a dup ki a yin lrun. O ye ki a yin. Halleluyah!

  Get Free and Complete Copies of my prayers books on 

UList at https://ulist.com.ng/bookshop or on Amazon https://www.amazon.com/author/thebestsellingauthorx

Father in Jesus name

I worship you you for your loving kindness.

Thank you for the grace you have given me.

Thank you for your outstretched arms for me.

Thank you Lord for your wonder and Miracles in my life.

Thank you for the successes I have recorded this year.

Thank you for the increase and your marvelous blessing.

Thank you for the sound health that you bestowed upon me and my loved ones.

Thank you for safety at every moment.

I worship you God in Jesus name.

I bless your name for the expansion and increase that I'm experiencing.

Thank you for loading me daily with your blessings.

Glory and honour be to your name in Jesus name.

I bless you oh God for the divine increase.

Thank you for the uplift and breakthroughs.

Thank you for the gift of life.

Thank you for the gift of Salvation in Jesus.

Thank you for safety from the evils that ravage the and the pestilence that ravage the night.

Thank you for multiplication and fruitfulness in my family and marriage.

Thank you for the increase my finances.

I worship you for the promotion in my job.

Thank you for the new deals that I'm sealing in my businesses.

Glory be to you oh God.

You are wonderful.

You are mighty.

You are gracious.

You are glorious.

You are the highest.

You are the best.

You are althe greatest God.

You are holy and righteous.

You are loving.

You are good and kind.

Glory to your name.

Even if I have ten thousand tongues, it is not enough to praise you.

I come with my token of sacrifice of praise with Thanksgiving.

Halleluyah.

The world is full of your beauty.

I give thanks to you for all that you have done, for all that you are doing and for all that you are going to do.

Thank you for the men and women positioned for my uplift.

Thank you for putting my enemies to shame.

Thank you for the opportunities that are coming my way.

Thank you for my good heart desires that have been granted.

Thank you for my expectations that are coming to Manifestation.

I bless your name for I am your light and glory and I shine everywhere.

Thank you for being there for me always.

Thank you because no one and nothing can stand against me.

You are absolutely wonderful oh God of my salvation.

I give thanks to you for your goodness endures forever.

I praises to your holy name, For your name is greatly to be praised.

I give praises to your name for yours mercies and compassion.

NO one is liked unto you oh God. You are glorious I in holiness, fearful in praises.

You are the King of kings and the Lord of Lords. The owner of the universe.

Oh Lord my God, my worship belongs to you. My praises belong to you.

Thank you for when my enemies attempted to kill and destroy, they failed and are put to shame.

Lord, you are wonderful. Your are more precious than silver, more precious than gold. Lord you are my beautiful than diamond.

I glorify you.

I magnify your name.

For your are good and your mercies endure forever.

Glory to you Oh God.

Halleluyah.

(speak in other tongues. Praise him)...

 

------

Adura Ope Lowo Olorun

 

Baba ni oruko Jesu.

Mo yin fun oore if r.

O eun fun oore-f ti o fun mi.

O eun fun awn owó ife r ti o nà si mi.

O eun Oluwa fun iyanu r ninu aye mi.

O eun fun awn aeyri ti Mo ti se ni dun yii.

O eun fun igbega ati ibukun iyanu r.

Mo dupe fun ilera to peye ti o fi fun emi ati awon ebi mi.

O eun fun aabo ni gbogbo igba.

Mo yin ó Olorun ni oruko Jesu.

Mo fibukun f'oruk r fun imugboro ati ibukun ti mo ń rí gba.

O eun fun akojp ibukun r fún mi lojoojumo.

Ogo ati la ni fun oruk r ni oruk Jesu. Mo fi ogo fun o olorun fun alekun atorunwa.

O eun fun Igbesoke ati awn àeyrí mi.

O eun fun ìwàláàyè mi.

O seun fun ebun Igbala ninu Jesu.

O eun pé ó pá mi mo kúrò nínú ibi tí ó ń fò ní osan ati ajakal-arun ti o fo li oru.

O eun fun isodipupo ati èso rere ninu idile ati ìgbéyàwó mi.

O eun fun ìbùkún owo. Mo yin fun igbega ni ibi iṣẹ mi.

O eun fun awn Contracts ti mon rí gbà nínú owó mi.

Ogo ni fun o Olorun.

 Iwo ni onise iyanu

Iwo ni oba alagbara

Iwo loba to kun fun oore-f

Ologo ni io Olorun.

Iw ni Oba to ga jul.
 Iwo loba to dara ju.

 Iw ni lrun ti o tobi jul.

 Mim ati olododo ni iw Oluwa.

Olorun ife ni O.

Ogo ni fun oruk r Oluwa.

Ti mo ba ni gbarun ahn, ko to lati yin o Olorun.

 Mo fi iyin pelu ebo Idupe fun o.

Halleluyah.

Aye kun fun ewa ati ogo re. Mo dup lw r fun gbogbo ohun ti o ti e, fun gbogbo ohun ti o ne ati fun gbogbo ohun ti iw yoo e.

O eun fun awn oluranlowo kunrin ati obinrin ti o gbe dide fun Igbega mi.

O seun ti o dojuti awon ota mi.

O eun fun awn anfani ti o n bow a fun mi.

O eun fun awnedun kan ti o dara ti o ti se funni.

O eun fun awn ireti mi ti o nb wa si imuse.

Mo fi ibukun fun oruko re, nitori Emi ni imole ati ogo re, mo si nmole nibi gbogbo.

O eun pe o n dami lohun nigbagbogbo ti mo ba kigbe pe o.

 O eun nitori ko si nikan tabi ohunkohun ti o le demi  lona lati se rere.

Iyanu ni o, Olorun igbala mi.

Mo dup lw r nitori aanu  r duro lailai.

Mo fiyin orúk mímọ́ r, Nítorí orúk r ní ìyìn lplp.

Mo fiyin oruko re fun ore ati aanu re.

 KO si enikan ti o dabi re o Olorun. Ologo didan ni o, elru ni iyin nio.

 Iw ni ba awn ba ati Oluwa awn Oluwa. Iwo ni eleda orun ati aye.

Oluwa Olorun mi, tire ni iyin ati ola.

O eun nitori pe, nigbati awn ta dide simi lati pa mi, wn kose, won si subu.

Oluwa, o j iyanu. Ìw níye lórí ju fàdákà l,ó sì eyebíye ju wúrà l. Oluwa iwo li ewa mi ju diamondi lo. Mo yin yin logo.

Mo gbé orúk r ga. Ogo ni fun O Olorun. Halleluyah.

(speak in other tongues. Praise him)...

WATCH THE VIDEOS AND PRAY ALONG


Subscribe to our youtube channel here.

Tags:

Post a Comment

0Comments

Post a Comment (0)